Members Advert

FÍDÍÒ: Ọ̀rọ̀ Kàbìtì: Bí mo ṣe pàdánù ọwọ́ mi méjèèjì lẹ́yìn ìkọlù Fúlàní -Bàbá àgbẹ̀ ẹni àádọ́rin ọdún

Eni àádọ́rin ọdún, Amodu Bakare, ti awon Fulani ge ni owo mejeeji ba wa soro ni ilu Itasa ni ipinle Oyo, nipa bi isele na se sele. Oba alade ilu Itasa, Oba Michael Oyediran, na salaye eyi ti won mo nipa isele na. Asi tun ba olori awon Fulani/Hausa to was ni ilu Itasa soro…

Read More